Ìṣe Àwọn Aposteli 5:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọ̀gá àwọn ẹ̀ṣọ́ ti Tẹmpili ati àwọn olórí alufaa gbọ́ ìròyìn yìí, ọkàn wọn dàrú; wọ́n ń ronú pé, irú kí ni eléyìí?

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:16-28