Ìṣe Àwọn Aposteli 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ àwọn eniyan wá láti agbègbè ìlú Jerusalẹmu, wọ́n ń gbé àwọn aláìsàn ati àwọn tí ẹ̀mí burúkú ń dà láàmú wá; a sì mú gbogbo wọn lára dá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:15-18