Ìṣe Àwọn Aposteli 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, àwọn eniyan a máa gbé àwọn aláìsàn wá sí títì lórí ẹní ati lórí ibùsùn, pé kí òjìji Peteru lè ṣíji bò wọ́n nígbà tí ó bá ń kọjá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:11-25