Ìṣe Àwọn Aposteli 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó láyà ninu àwọn ìyókù láti darapọ̀ mọ́ wọn. Ọ̀rọ̀ wọn níyì lọ́dọ̀ àwọn eniyan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:7-17