Ìṣe Àwọn Aposteli 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu ni àwọn aposteli ṣe láàrin àwọn eniyan. Gbogbo wọn wà ní ìṣọ̀kan ní ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí wọn ń pè ní ti Solomoni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:3-17