Ìṣe Àwọn Aposteli 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ó má baà tún máa tàn kálẹ̀ sí i láàrin àwọn eniyan, ẹ jẹ́ kí á kìlọ̀ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ dárúkọ Jesu fún ẹnikẹ́ni mọ́.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:14-24