Ìṣe Àwọn Aposteli 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí ni a óo ṣe sí àwọn ọkunrin wọnyi o? Nítorí ó hàn lónìí sí gbogbo àwọn tí ó ń gbé Jerusalẹmu pé wọ́n ti ṣe iṣẹ́ abàmì. A kò sì lè wí pé èyí kò rí bẹ́ẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Ìṣe Àwọn Aposteli 4:15-19