Ìṣe Àwọn Aposteli 3:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn wolii, láti ìgbà Samuẹli ati àwọn tí ó dé lẹ́yìn rẹ̀, fi ohùn ṣọ̀kan sí ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n ń sọ nípa àkókò yìí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:23-26