Ìṣe Àwọn Aposteli 3:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá gbọ́ràn sí wolii náà lẹ́nu, píparun ni a óo pa á run patapata láàrin àwọn eniyan Ọlọrun.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Ìṣe Àwọn Aposteli 3:13-26