Ìṣe Àwọn Aposteli 28:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń waasu ìjọba Ọlọrun. Ó ń kọ́ àwọn eniyan nípa Oluwa Jesu Kristi láì bẹ̀rù ohunkohun. Ẹnikẹ́ni kò sì dí i lọ́wọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:29-31