Ìṣe Àwọn Aposteli 28:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún ọdún meji gbáko ni Paulu fi gbé ninu ilé tí ó gbà fúnra rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni ó ń gba gbogbo àwọn tí ó ń wá rí i.

Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:21-31