Ìṣe Àwọn Aposteli 27:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, wọ́n rí èbúté ṣugbọn wọn kò mọ ibẹ̀. Wọ́n wá ṣe akiyesi ibìkan tí òkun ti wọ ààrin ilẹ̀ tí ó ní iyanrìn. Wọ́n rò pé bóyá àwọn lè tukọ̀ dé èbúté ibẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:30-44