Ìṣe Àwọn Aposteli 27:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jẹun yó tán, wọ́n da ọkà tí ó kù sinu òkun láti mú kí ọkọ̀ lè fúyẹ́ sí i.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:33-44