Ìṣe Àwọn Aposteli 27:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, òun náà mú burẹdi, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun níwájú gbogbo wọn, ó bù ú, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí jẹ ẹ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:26-37