Ìṣe Àwọn Aposteli 27:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo bẹ̀ yín, ẹ jẹun; èyí ṣe pataki bí ẹ ò bá fẹ́ kú. Irun orí ẹnikẹ́ni kò tilẹ̀ ní ṣòfò.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:29-39