Ìṣe Àwọn Aposteli 27:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ogun bá gé okùn tí wọ́n fi so ọkọ̀ kékeré náà, wọ́n jẹ́ kí ìgbì gbé e lọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:24-38