Ìṣe Àwọn Aposteli 27:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu wá sọ fún balogun ọ̀rún ati àwọn ọmọ-ogun náà pé, “Bí àwọn ará ibí yìí kò bá dúró ninu ọkọ̀, kò sí bí ẹ ti ṣe lè là.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:23-40