Ìṣe Àwọn Aposteli 27:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá ń bẹ̀rù pé kí ọkọ̀ má forí sọ òkúta. Wọ́n bá ju irin ìdákọ̀ró mẹrin sinu omi ní ẹ̀yìn ọkọ̀; wọ́n bá ń gbadura pé kí ilẹ̀ tètè mọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:25-33