Ìṣe Àwọn Aposteli 27:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ ìwọ̀n sinu òkun, wọ́n rí i pé ó jìn tó ogoji mita. Nígbà tí a sún díẹ̀, wọ́n tún sọ ìwọ̀n sinu òkun, wọ́n rí i pé ó jìn tó ọgbọ̀n mita.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:25-33