Ìṣe Àwọn Aposteli 27:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún ọpọlọpọ ọjọ́ ni oòrùn kò ràn tí ìràwọ̀ kò sì yọ. Ìjì ńlá ń jà. A bá sọ ìrètí nù pé a tún lè là mọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:10-26