Ìṣe Àwọn Aposteli 27:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹta, ọwọ́ ara wọn ni wọ́n fi da àwọn ohun èèlò inú ọkọ̀ náà sinu òkun.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:11-28