Ìṣe Àwọn Aposteli 27:16 BIBELI MIMỌ (BM)

A sinmi díẹ̀ nígbà tí a gba gúsù erékùṣù kékeré kan tí ó ń jẹ́ Kauda kọjá. Níbẹ̀, a fi tipátipá so ọkọ̀ kékeré tí ó wà lára ọkọ̀ ńlá wa, kí ó má baà fọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Ìṣe Àwọn Aposteli 27:14-22