Ìṣe Àwọn Aposteli 25:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Fẹstu dá wọn lóhùn pé, “Àwọn ọmọ-ogun ń ṣọ́ Paulu ní Kesaria; èmi náà kò sì ní pẹ́ pada sibẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:1-8