Ìṣe Àwọn Aposteli 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ó ṣe oore kan fún wọn, kí ó fi Paulu ranṣẹ sí Jerusalẹmu. Èrò wọn ni láti dènà dè é, kí wọ́n baà lè pa á.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:1-5