Ìṣe Àwọn Aposteli 25:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo dá wọn lóhùn pé kì í ṣe àṣà àwọn ará Romu láti fa ẹnikẹ́ni lé àwọn olùfisùn rẹ̀ lọ́wọ́ láì fún un ní anfaani láti fojúkojú pẹlu wọn, kí ó sì sọ ti ẹnu rẹ̀ nípa ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:14-23