Ìṣe Àwọn Aposteli 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo lọ sí Jerusalẹmu, àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbààgbà àwọn Juu rojọ́ rẹ̀, wọ́n sì bẹ̀ mí pé kí n dá a lẹ́bi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Ìṣe Àwọn Aposteli 25:10-19