Ìṣe Àwọn Aposteli 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ iwájú ni ẹ̀ ń rò tí ẹ fi ń ṣe èyí nígbà gbogbo. A dúpẹ́ pupọ lọ́wọ́ yín.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:1-9