Ìṣe Àwọn Aposteli 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n pe Paulu, Tatulu bẹ̀rẹ̀ sí rojọ́. Ó ní:“Fẹliksi ọlọ́lá jùlọ, à ń jọlá alaafia tí ẹ mú wá lọpọlọpọ, a sì ń gbádùn oríṣìíríṣìí àtúnṣe tí ẹ̀ ń ṣe lọ́tùn-ún lósì fún àwọn ọmọ ilẹ̀ wa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Ìṣe Àwọn Aposteli 24:1-8