Ìṣe Àwọn Aposteli 23:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji wọ́n fi Paulu sílẹ̀ pẹlu àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣin, wọ́n pada sí àgọ́ wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:30-33