Ìṣe Àwọn Aposteli 23:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ogun ṣe bí a ti pàṣẹ fún wọn. Wọ́n mú Paulu lóru lọ sí ìlú Antipatiri.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:25-35