Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àríyànjiyàn náà pọ̀ pupọ, ẹ̀rù ba ọ̀gágun pé kí wọn má baà fa Paulu ya. Ó bá pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ogun kí wọn wá fi agbára mú Paulu kúrò láàrin wọn, kí wọn mú un wọnú àgọ́ àwọn ọmọ-ogun lọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Ìṣe Àwọn Aposteli 23:7-13