Ìṣe Àwọn Aposteli 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Juu ni mí, Tasu ní ilẹ̀ Silisia la gbé bí mi. Ní ìlú yìí ni a gbé tọ́ mi dàgbà. Ilé-ìwé Gamalieli ni mo lọ, ó sì kọ́ mi dáradára nípa Òfin ìbílẹ̀ wa. Mo ní ìtara fún Ọlọrun gẹ́gẹ́ bí gbogbo yín ti ní lónìí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:1-9