Ìṣe Àwọn Aposteli 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́ tí ó ń bá wọn sọ̀rọ̀ ní èdè Heberu, wọ́n pa lọ́lọ́. Paulu bá bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀, ó ní,

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:1-8