Ìṣe Àwọn Aposteli 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, a gbéra, a lọ sí Kesaria. A wọ ilé Filipi, ajíyìnrere, ọ̀kan ninu àwọn meje tí àwọn ìjọ Jerusalẹmu yàn ní ijọ́sí. Lọ́dọ̀ rẹ̀ ni a dé sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:3-10