Ìṣe Àwọn Aposteli 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti Tire, a bá ń bá ìrìn àjò wa lọ títí a fi dé Tolemaisi. Níbẹ̀ a lọ kí àwọn onigbagbọ, a sì dúró lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ kan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1-16