Ìṣe Àwọn Aposteli 21:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọjọ́ tí a óo gbé níbẹ̀ pé, a gbéra láti máa bá ìrìn àjò wa lọ. Gbogbo wọn ati àwọn iyawo wọn ati àwọn ọmọ wọn sìn wá dé ẹ̀yìn odi. A bá kúnlẹ̀ lórí iyanrìn ní èbúté, a gbadura.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1-12