Ìṣe Àwọn Aposteli 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

A bá àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu kan níbẹ̀, a bá dúró tì wọ́n níbẹ̀ fún ọjọ́ meje. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu yìí sọ ohun tí Ẹ̀mí Mímọ́ fihàn wọ́n fún Paulu pé kí ó má lọ sí Jerusalẹmu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1-13