Ìṣe Àwọn Aposteli 21:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé àtẹ̀gùn ilé, gbígbé ni àwọn ọmọ-ogun níláti gbé Paulu wọlé nítorí ojú àwọn èrò ti ranko.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:27-39