Ìṣe Àwọn Aposteli 21:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan ninu èrò ń sọ nǹkankan; àwọn mìíràn ń sọ nǹkan mìíràn. Nígbà tí ọ̀gágun náà kò lè mọ òtítọ́ ọ̀rọ̀ náà nítorí ariwo èrò, ó pàṣẹ pé kí wọ́n mú Paulu lọ sí àgọ́ àwọn ọmọ-ogun.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:30-36