Ìṣe Àwọn Aposteli 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n fi ògo fún Ọlọrun. Àwọn náà wá sọ fún un pé, “Wò ó ná, arakunrin, ṣé o mọ̀ pé ẹgbẹẹgbẹrun ni àwọn Juu tí ó gba Jesu gbọ́, tí gbogbo wọn sì ní ìtara sí Òfin Mose.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:18-26