Ìṣe Àwọn Aposteli 21:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Paulu kí wọn tán, ó ròyìn lẹ́sẹẹsẹ iṣẹ́ tí Ọlọrun lo òun láti ṣe láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:18-24