Ìṣe Àwọn Aposteli 20:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní alẹ́ ọjọ́ Satide, a péjọ láti jẹun; Paulu wá ń bá àwọn onigbagbọ sọ̀rọ̀. Ó ti wà lọ́kàn rẹ̀ pé lọ́jọ́ keji ni òun óo tún gbéra. Nítorí náà ó sọ̀rọ̀ títí dòru.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:5-17