Ìṣe Àwọn Aposteli 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa náà wá wọkọ̀ ojú omi ní Filipi lẹ́yìn Àjọ̀dún Àìwúkàrà, a bá wọn ní Tiroasi lọ́jọ́ karun-un. Ọjọ́ meje ni a lò níbẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:4-9