Ìṣe Àwọn Aposteli 20:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti fihàn yín pé bẹ́ẹ̀ ni a níláti ṣiṣẹ́ láti ran àwọn aláìlera lọ́wọ́. Kí á máa ranti àwọn ọ̀rọ̀ Oluwa Jesu, nítorí òun fúnra rẹ̀ sọ pé, ‘Ayọ̀ pọ̀ ninu kí a máa fúnni ní nǹkan ju kí á máa gbà lọ.’ ”

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:29-38