Ìṣe Àwọn Aposteli 20:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin fúnra yín mọ̀ pé ọwọ́ ara mi yìí ni mo fi ṣiṣẹ́ tí mo fi ń gbọ́ bùkátà mi ati ti àwọn ẹlẹgbẹ́ mi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:24-38