Ìṣe Àwọn Aposteli 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń kọjá ní gbogbo agbègbè náà, bẹ́ẹ̀ ni ó ń gba àwọn eniyan níyànjú pẹlu ọ̀rọ̀ ìwúrí pupọ títí ó fi dé ilẹ̀ Giriki.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:1-9