Ìṣe Àwọn Aposteli 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí rògbòdìyàn náà kásẹ̀, Paulu ranṣẹ pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu. Ó gbà wọ́n níyànjú, ó sì dágbére fún wọn, ó bá lọ sí Masedonia.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:1-3