Ìṣe Àwọn Aposteli 2:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan gbọ́, ọ̀rọ̀ náà gún wọn lọ́kàn. Wọ́n wá bi Peteru ati àwọn aposteli yòókù pé, “Ẹ̀yin ará, kí ni kí á wá ṣe?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:35-44