Ìṣe Àwọn Aposteli 2:36 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà kí gbogbo ilé Israẹli mọ̀ dájú pé Jesu yìí tí ẹ̀yin kàn mọ́ agbelebu ni Ọlọrun ti fi ṣe Oluwa ati Mesaya!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:27-41