Ìṣe Àwọn Aposteli 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn yóo ṣókùnkùn, òṣùpá yóo di ẹ̀jẹ̀,kí ó tó di ọjọ́ ńlá tí ó lókìkí, ọjọ́ Oluwa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:14-24